Add parallel Print Page Options

(A)A máa faradà ohun gbogbo sí òtítọ́, a máa gba ohun gbogbo gbọ́, a máa retí ohun gbogbo, a máa fàyàrán ohun gbogbo.

Ìfẹ́ kì í kùnà láé, kì í sì í yẹ̀ ṣùgbọ́n bí ó bá ṣe ìsọtẹ́lẹ̀ ni, wọn yóò dópin, bí ó bá ṣe ẹ̀bùn ahọ́n ni, wọn yóò dákẹ́, bí ó bá ṣe pé ìmọ̀ ni yóò di asán.

Read full chapter

It always protects, always trusts, always hopes, always perseveres.(A)

Love never fails. But where there are prophecies,(B) they will cease; where there are tongues,(C) they will be stilled; where there is knowledge, it will pass away.

Read full chapter