Add parallel Print Page Options

21 “Ẹni tí kò níláárí kan yóò rọ́pò rẹ̀, ẹni tí a kò tí ì fi ọlá ọba fún rí. Yóò sì gbógun sí ìjọba nígbà tí ọkàn àwọn ènìyàn balẹ̀ láìbẹ̀rù, yóò sì gbà á pẹ̀lú àrékérekè.

Read full chapter

21 “He will be succeeded by a contemptible(A) person who has not been given the honor of royalty.(B) He will invade the kingdom when its people feel secure, and he will seize it through intrigue.

Read full chapter