Add parallel Print Page Options

16 There is ruin and suffering wherever they go.
17 They have not learned to live in peace.
18 They are not terrified of God.”

Read full chapter

16     ìparun àti ìpọ́njú wà lọ́nà wọn.
17 Ọ̀nà àlàáfíà ni wọn kò sì mọ̀:”
18     (A)“Ìbẹ̀rù Ọlọ́run kò sí níwájú wọn.”

Read full chapter